Skip to main content

Full text of "The Holy Bible in Yoruba"

See other formats


IWE KINI MOSE, 

TI A NPE NI 

GENESISI 



ORI 1 

LI atetekp$e Qlprun da prun on 
-/ aiye. 

2 Aiye si wa ni juju, o si ?ofo; 6ku- 
nkun si wa loju ibu: pmi Qlprun si 
nrababa loju omi. 

3 Qlprun si wipe, Ki imple ki o wa: 
imple si wa. 

4 Qlprun si ri imple na, pe o dara: 
Qlprun si pala si agbedemeji imple on 
dkunkun. 

5 Qlprun si pe imple ni Qsan, ati 
dkunkun ni Oru. Ati a§ale ati owurp 
o di pjp kini. 

6 Qlprun si wipe, Ki ofurufu ki o 
wa li agbedemeji omi, ki o si ya omi 
kuro lara omi. 

7 Qlprun si $e ofurufu, o si ya omi 
ti o wa nisale ofurufu kuro lara omi ti 
o wa loke ofurufu: o si ri b$. 

8 Qlprun si pe ofurufu ni Qrun. 
Ati a$ale ati owurp o di pjp keji. 

9 Qlprun si wipe, Ki omi abe prun 
ki o wpjp pp si ibi kan, ki iyangbe ile 
ki o si han: o si ri b$. 

10 Qlprun si pe iyangbe ile ni lie; 
o si pe iwpjppp omi ni Okun: Qlprun 
si ri pe o dara. 

11 Qlprun si wipe, Ki ile ki o hu 
oko, eweko ti yio ma so eso, ati igi 
eleso ti yio ma so eso ni iru tire, ti o ni 
irugbin ninu lori ile : o si ri b<?. 

12 lie si su koriko jade, eweko ti 
nso eso ni iru tire, ati igi ti nso eso, ti 
o ni irugbin ninu ni iru tir$: Qlprun si 
ri pe o dara. 

13 Ati a§ale ati owurp o di pjp 
keta. 

14 Qlprun si wipe, Ki awpn imple ki 
o wa li ofurufu prun, lati pala psan 
on oru; ki nwpn ki o si ma wa fun 



ami, ati fun akoko, ati fun pjp, ati 
fun pdun: 

15 Ki nwpn ki o si j£ imple li ofu- 
rufu prun, lati mple sori ile: o si ri b?. 

16 Qlprun si da imple nla meji; 
imple ti o tobi lati §e akoso psan, ati 
imple ti o kere lati §e akoso oru: o si 
da awpn irawp pelu. 

17 Qlprun si sp wpn lpjp li ofurufu 
prun, lati ma tan imple sori ile, 

18 Ati lati §e akoso psan ati akoso 
oru, ati lati pala imple on dkunkun: 
Qlprun si ri pe o dara. 

19 Ati a§ale ati owurp o di pjp kerin. 

20 Qlprun si wipe, Ki omi ki o kun fun 
ppplppp eda alaye ti nrak6, ati ki eiye 
ki o ma fo loke ile li oju-ofurufu prun. 

21 Qlprun si da erinmi nlanla ati 
eda alaye gbogbo ti nrakd, ti omi kun 
fun li ppplppp ni iru wpn, ati eiye 
abiye ni iru r?: Qlprun si ri pe o dara. 

22 Qlprun si sure fun wpn pe, E ma 
bi si i, e si ma r?, ki e kun inu omi li 
okun, ki eiye ki o si ma r£ ni ile. 

23 Ati a§ale ati owurp o di pjp karun. 

24 Qlprun si wipe, Ki ile ki o mu 
eda alaye ni iru r£ jade wa, eran-psin, 
ati ohun ti nrakp, ati eranko ile ni iru 
r£: o si ri b$. 

25 Qlprun si da eranko ile ni iru 
tir?, ati eran-psin ni iru tir^, ati ohun 
gbogbo ti nrakb lori ile ni iru tir£: 
Qlprun si ri pe o dara, 

26 Qlprun si wipe, Je ki a da enia li 
aworan wa, gege bi in wa: ki nwpn ki 
o si jpba lori eja okun, ati lori eiye 
oju-prun, ati lori eranko, ati lori 
gbogbo ile, ati lori ohun gbogbo ti 
nrakd lori ile. 

27 B§li Qlprun da enia li aworan r£, 
li aworan Qlprun li o da a; ati akp ati 
abo li o da wpn. 



6 



GENESISI 2, 3 



28 Qlprun si sure fun wpn. Qlprun 
si wi fun wpn pe, 5 ma bi si i, ki e si 
ma r$, ki e si gbile, ki e si §e ikawp r^; 
ki e si ma jpba lori eja okun, ati lori 
eiye oju-prun, ati lori ohun alaye gbo- 
gbo ti nrako lori ile. 

29 Qlprun si wipe, kiye si i, Mo fi 
eweko gbogbo ti o wa lori ile gbogbo ti 
nso eso fun nyin, ati igi gbogbo ninu 
eyiti i$e igi eleso ti nso; enyin ni yio 
ma $e onje fun. 

30 Ati fun gbogbo eranko ile, ati 
fun gbogbo eiye oju-prun, ati fun ohun 
gbogbo ti o nrako lori ile, ti i$e alaye, 
ni mo fi eweko tutu gbogbo fun li onje: 
o si ri b§. 

31 Qlprun si ri ohun gbogbo ti o da, 
si kiyesi i, daradara ni. Ati a§ale ati 
owurp o di pjp kefa. 

ORI 2 

BE li a pari prun on aiye, ati gbo- 
gbo ogun wpn. 

2 Ni ijp keje Qlprun si pari i§e r£ ti 
o ti n§e ; o si simi ni ijp keje kuro ninu 
i§e r£ gbogbo ti o ti n§e. 

3 Qlprun si busi ijp keje, o si ya a si 
mimp ; nitori pe, ninu r$ li o simi kuro 
ninu i§e r£ gbogbo ti o ti b$re si i§e. 

4 Itan prun on aiye ni wpnyi nigbati 
a da wpn, li pj<> ti Oluwa Qlprun da 
aiye on prun. 

5 Ati olukuluku igi igbe ki o to wa 
ni ile, ati olukuluku eweko igbe ki nwpn 
ki o to hu: Oluwa Qlprun ko sa ti 
rpjo si ile, ko si si enia kan lati ro ile. 

6 $ugbpn ikuku a ti ile wa, a si ma 
rin oju ile gbogbo. 

7 Oluwa Qlprun si fi erupe ile mp 
enia; o si mi emi iye si iho imu r£; 
enia si di alaye pkan. 

8 Oluwa Qlprun si gbin pgba kan 
niha ilaorun ni Edeni; nib$ H o si fi 
pkpnrin na ti o ti mp si. 

9 Lati inu ile li Oluwa Qlprun mu 
oniruru igi hu jade wa, ti o dara ni 
wiwo, ti o si dara fun onje; igi iye pelu 
larin pgba na, ati igi imp rere ati 
buburu. 

10 Odd kan si ti Edeni $an wa lati 
rin pgba na; lati ib£ li o gb6 ya, o si di 
ipa ori merin. 

11 Orukp ekini ni Pisoni: on li eyiti 
o yi gbogbo ile Hafila kd, nibiti wura 
wa; 



12 Wura ile na si dara: nibe ni 
bedeliumu (ojia) wa ati okuta oniki. 

13 Orukp odd keji si ni Gihoni: on 
na li eyiti o yi gbogbo ile Ku$i ka. 

14 Ati orukp odo keta ni Hiddekeli : 
on li eyiti n$an lp si iha iha-orun Assi- 
ria. Ati odd kerin ni Euferate. 

1 5 Oluwa Qlprun si mu pkpnrin na, 
o si fi i sinu pgba Edeni lati ma ro o, 
ati lati ma $p p. 

16 Oluwa Qlprun si fi a§e fun pkp- 
nrin na pe, Ninu gbogbo igi pgba ni ki 
iwp ki o ma je : 

17 $ugbpn ninu igi imp rere ati 
bururu ni, iwp ko gbpdp je ninu r£: 
nitoripe li pjp ti iwp ba je ninu r$ kiku 
ni iwp o ku. 

18 Oluwa Qlprun si wipe, ko dara 
ki pkpnrin na lei o nikan ma gbe; emi 
o §e oluranlpwp ti o dabi r^ fun u. 

19 Lati inu ile li Oluwa Qlprun si 
ti da eranko igbe gbogbo, ati eiye oju- 
prun gbogbo; o si mu wpn tp Adamu 
wa lati wo orukp ti yio sp wpn ; orukp- 
korukp ti Adamu si sp olukuluku eda 
alaye, on li orukp r$. 

20 Adamu si sp eran-psin gbogbo, 
ati eiye oju-prun, ati eranko igbe 
gbogbo, li orukp; §ugbpn fun Adamu 
a ko ri oluranlpwp ti o dabi r£ fun u. 

21 Oluwa Qlprun si mu orun ijika 
kun Adamu, o si sun: o si yp pkan ninu 
egungun-iha r^, o si fi eran di ipo r^ : 

22 Oluwa Qlprun si fi egungun-iha 
ti o mu ni iha pkpnrin na mp obirin, o 
si mu u tp pkpnrin na wa. 

23 Adamu si wipe, Eyiyi li egungun 
ninu egungun mi, ati eran-ara ninu era- 
nara mi: Obirin li a o ma pe e, nitori 
ti a mu u jade lati ara pkpnrin wa. 

24 Nitori na li pkpnrin yio $e ma fi 
baba on iya r£ sile, yio si fi ara mp aya 
r£: nwpn o si di ara kan. 

25 Awpn mejeji si wa ni ihoho, ati 
pkpnrin na ati obirin r?, nwpn ko si 
tiju. 

ORI 3 

EjC) sa §e arakereke ju eranko igbe 
iyoku lp ti Oluwa Qlprun ti da. 
O si wi fun obirin na pe, otp li Qlprun 
wipe, £nyin ko gbpdp je gbogbo eso igi 
pgba? 

2 Obirin na si wi fun ejd na pe, Awa 
a ma je ninu eso igi pgba: 



GENESISI 



3 §ugbpn ninu eso igi ni ti o wk 
larin pgba Qlprun ti wipe, pnyin k6 
gbpdp ninu r$, bfli $nyin ko gbpdp 
fpwpkan a, ki enyin ki o ma ba ku. 

4 Ejo na si wi fun obirin na pe, 
Enyin ki yio ku iku kikii kan. 

5 Nitori Qlprun mp pe, li pjp ti 
$nyin ba }§ ninu r$, nigbana li oju nyin 
yio la, enyin o si dabi Qlprun, e o mp 
rere ati bururu. 

6 Nigbati obirin na si ri pe, igi na 
dara ni jije, ati pe, o si dara fun oju, ati 
igi ti a if$ lati mu ni gbpn, o mu ninu 
eso r$ o si j$, o si fi fun pkp r$ p$lu r£, 
on si if . 

7 Oju awpn mejeji si la, nwpn si mp 
pe nwpn wa ni ihoho ; nwpn si gan 
ewe ppptp pp, nwpn si da ibant$ fun 
ara wpn. 

8 Nwpn si gbp ohun Oluwa Qlp- 
run, o nrin ninu pgba ni itura pjp: 
Adamu ati aya r£ si fi ara wpn pamp 
kuro niwaju Oluwa Qlprun larin igi 

pgba. 

9 Oluwa Qlprun si kp si Adamu, o 
si wi fun u pe, Nibo ni iwp wa 7 

10 O si wipe, Mo gbp ohun r§ ninu 
pgba, £ru si ba mi, nitori ti mo wa ni 
ihoho; mo si fi ara pamp. 

11 O si wi pe, Tali o wi fun p pe iwp 
wa ni ihoho ? iwp ha 3$ ninu igi ni, ninu 
eyiti mo pa§$ fun p pe iwp ko gbpdp 

12 Qkpnrin na si wipe, Obirin ti iwp 
fi p$lu mi, on li o fun mi ninu eso igi 
na, emi si 

1 3 Oluwa Qlprun si bi obirin na pe, 
Ewo ni iwp §e yi ? Obirin na si wipe, 
Ejo li o tan mi, mo si j$. 

14 Oluwa Qlprun si wi fun ejo na 
pe, nitori ti iwp ti §e eyi, a fi iwp bu 
ninu gbogbo $ran ati ninu gbogbo 
eranko igb?; inu r$ ni iwp o ma fi wp, 
erup? il$ ni iwp o ma j$ li pj$ aiye r$ 
gbogbo. 

15 Emi o si fi pta sarin iwp ati obirin 
na, ati sarin iru-pmp r$ ati iru-pmp r£ : 
on o fp p li ori, iwp o si pa a ni gigis$. 

16 Fun obirin na li o wipe, Emi o 
sp ippnju ati iloyun r$ di pupp; ni 
ippnju ni iwp o ma bimp; lpdp pkp i§ 
ni ifip r$ yio ma fa si, on ni yio si ma §e 
olori r$. 

17 O si wi fun Adamu pe, Nitori ti 
iwp gba ohun aya r$ gbp, ti iwp si j$ 



7 

ninu eso igi na, ninu eyiti mo ti pa§$ 
fun p pe, iwp kd gbpdp j$ ninu r$; a fi 
il$ bu nitori r$; ni ippnju ni iwp o ma 
je ninu r£ li pjp aiye r$ gbogbo; 

18 pgun on o?u$u m yio ma hu jade 
fun p, iwp o si ma j$ eweko igb$: 

19 Li dgun oju r$ ni iwp o ma j$un, 
titi iwp o fi pada si il$; nitori inu r£ li 
a ti mu p wa, erup$ sa ni iwp, iwp o si 
pada di erup$. 

20 Adamu si peorukp aya r$niEfa; 
nitori on ni i§e iya alaye gbogbo. 

21 Ati fun Adamu ati fun aya li 
Oluwa Qlprun da ewu awp, o si fi wp 
wpn. 

22 Oluwa Qlprun si wipe, Wo o, 
Qkpnrin na dabi pkan ninu wa lati m$ 
rere ati bururu: nj$ nisisiyi ki o ma ba 
na pwp r^ ki o si mu ninu eso igi iye 
Pflu, ki o si j^, ki o si yd titi lai; 

23 Nitorina Oluwa Qlprun le e jade 
kuro ninu pgba Edeni, lati ma ro il? 
ninu eyiti a ti mu u jade wa. 

24 Bfli o le pkpnrin na jade; o si fi 
awpn kerubu ati ida ina dt iha ila-drun 
Edeni ti nju kakiii, lati ma §p pna igi 
iye na. 



THE HOLY BIBLE IN YORUBA 

O.T. Reprinted from the Edition of 1900 
N.T. Corrected 1959 
© U.B.S. 1960 
EPF-BFBS- 1 99 1 -70M-OV53